Jẹnẹsisi 23:11 BM

11 “Rárá o! oluwa mi, gbọ́, mo fún ọ ní ilẹ̀ náà, ati ihò tí ó wà ninu rẹ̀, lójú gbogbo àwọn eniyan mi ni mo sì ti fún ọ, lọ sin aya rẹ sibẹ.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 23

Wo Jẹnẹsisi 23:11 ni o tọ