19 Lẹ́yìn náà, Abrahamu lọ sin òkú Sara sinu ihò ilẹ̀ Makipela, tí ó wà ní ìhà ìlà oòrùn Mamure, ní agbègbè Heburoni ní ilẹ̀ Kenaani.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 23
Wo Jẹnẹsisi 23:19 ni o tọ