Jẹnẹsisi 24:15 BM

15 Kí ó tó dákẹ́ adura rẹ̀ ni Rebeka ọmọ Betueli yọ sí i pẹlu ìkòkò omi ní èjìká rẹ̀. Ọmọ Nahori ni Betueli jẹ́, tí Milika bí fún un. Nahori yìí jẹ́ arakunrin Abrahamu.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 24

Wo Jẹnẹsisi 24:15 ni o tọ