18 Ọmọbinrin náà dáhùn pé, “Omi nìyí, oluwa mi.” Ó sì yára gbé ìkòkò rẹ̀ lé ọwọ́ rẹ̀ láti fún un ní omi mu.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 24
Wo Jẹnẹsisi 24:18 ni o tọ