20 Kíá, ó ti da omi tí ó kù ninu ìkòkò rẹ̀ sinu agbada tí ẹran fi ń mu omi, ó sáré pada lọ pọn sí i, títí tí gbogbo wọn fi mu omi káríkárí.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 24
Wo Jẹnẹsisi 24:20 ni o tọ