33 Wọ́n gbé oúnjẹ wá fún un pé kí ó jẹ, ṣugbọn ó wí pé, “N kò ní jẹun títí n óo fi jíṣẹ́ tí wọ́n rán mi.” Labani dáhùn, ó ní, “À ń gbọ́.”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 24
Wo Jẹnẹsisi 24:33 ni o tọ