Jẹnẹsisi 24:46 BM

46 Kíá ni ó sọ ìkòkò omi rẹ̀ kúrò ní èjìká, tí ó sì wí pé, ‘Omi nìyí, mu, n óo pọn fún àwọn ràkúnmí rẹ pẹlu.’ Mo bá mu omi, ó sì fún àwọn ràkúnmí mi lómi mu pẹlu.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 24

Wo Jẹnẹsisi 24:46 ni o tọ