Jẹnẹsisi 24:48 BM

48 Nígbà náà ni mo tẹríba, mo sì sin OLUWA, mo yin OLUWA Ọlọrun Abrahamu, oluwa mi lógo, ẹni tí ó tọ́ mi sí ọ̀nà tààrà láti wá fẹ́ ọmọ ẹbí oluwa mi fún ọmọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 24

Wo Jẹnẹsisi 24:48 ni o tọ