20 Nígbà tí Isaaki di ẹni ogoji ọdún, ó fẹ́ Rebeka. Rebeka jẹ́ ọmọ Betueli, ará Aramea, tí ń gbé Padani-aramu, ó sì tún jẹ́ arabinrin Labani, ara Aramea.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 25
Wo Jẹnẹsisi 25:20 ni o tọ