Jẹnẹsisi 25:23 BM

23 OLUWA wí fún un pé,“Orílẹ̀-èdè meji ni ó wà ninu rẹ,a óo sì pín àwọn oríṣìí eniyan meji tí o óo bí níyà,ọ̀kan yóo lágbára ju ekeji lọ,èyí ẹ̀gbọ́n ni yóo sì máa sin àbúrò.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 25

Wo Jẹnẹsisi 25:23 ni o tọ