Jẹnẹsisi 25:27 BM

27 Nígbà tí àwọn ọmọ náà dàgbà, Esau di ògbójú ọdẹ, a sì máa lọ sí oko ọdẹ nígbà gbogbo, ṣugbọn Jakọbu jẹ́ eniyan jẹ́jẹ́, ilé ni ó sì máa ń sábà gbé ní tirẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 25

Wo Jẹnẹsisi 25:27 ni o tọ