Jẹnẹsisi 25:34 BM

34 Jakọbu bá fún Esau ní àkàrà ati ẹ̀bẹ ati ẹ̀fọ́. Nígbà tí Esau jẹ, tí ó mu tán, ó bá tirẹ̀ lọ. Bẹ́ẹ̀ ni Esau ṣe fi ojú tẹmbẹlu ipò àgbà rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 25

Wo Jẹnẹsisi 25:34 ni o tọ