Jẹnẹsisi 26:15 BM

15 Gbogbo kànga tí àwọn iranṣẹ Abrahamu baba rẹ̀ gbẹ́ ní àkókò tí Abrahamu wà láyé ni àwọn ará Filistia rọ́ yẹ̀ẹ̀pẹ̀ dí.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 26

Wo Jẹnẹsisi 26:15 ni o tọ