28 Wọ́n dáhùn pé, “A rí i dájú pé OLUWA wà pẹlu rẹ, ni a bá rò pé, ó yẹ kí àdéhùn wà láàrin wa, kí á sì bá ọ dá majẹmu,
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 26
Wo Jẹnẹsisi 26:28 ni o tọ