18 Ni Jakọbu bá tọ baba rẹ̀ lọ, ó pè é, ó ní, “Baba mi,” Baba rẹ̀ bá dá a lóhùn pé, “Èmi nìyí ọmọ mi, ìwọ ta ni?”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 27
Wo Jẹnẹsisi 27:18 ni o tọ