Jẹnẹsisi 27:25 BM

25 Nígbà náà ni ó wí pé, “Gbé oúnjẹ náà súnmọ́ mi, kí n jẹ ninu ẹran tí ọmọ mi pa, kí n sì súre fún ọ.” Jakọbu bá gbé oúnjẹ náà súnmọ́ ọn, ó jẹ ẹ́, ó bu ọtí waini fún un, ó sì mu ún.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 27

Wo Jẹnẹsisi 27:25 ni o tọ