Jẹnẹsisi 27:43 BM

43 Nítorí náà, ọmọ mi, gbọ́ ohun tí n óo sọ fún ọ yìí, wá gbéra kí o sálọ bá Labani, arakunrin mi, ní Harani.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 27

Wo Jẹnẹsisi 27:43 ni o tọ