Jẹnẹsisi 28:13 BM

13 OLUWA pàápàá dúró lókè rẹ̀, ó wí fún un pé, “Èmi ni OLUWA Ọlọrun Abrahamu baba rẹ ati Ọlọrun Isaaki, ilẹ̀ tí o dùbúlẹ̀ sí yìí, ìwọ ati àwọn ọmọ rẹ ni n óo fi fún.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 28

Wo Jẹnẹsisi 28:13 ni o tọ