Jẹnẹsisi 28:16 BM

16 Nígbà tí Jakọbu tají ní ojú oorun rẹ̀, ó ní, “Dájúdájú OLUWA ń bẹ níhìn-ín, n kò sì mọ̀!”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 28

Wo Jẹnẹsisi 28:16 ni o tọ