14 Labani bá dá a lọ́kàn le, ó ní, “Láìsí àní àní, ẹ̀jẹ̀ kan náà ni wá” Jakọbu sì wà lọ́dọ̀ rẹ̀ fún oṣù kan.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 29
Wo Jẹnẹsisi 29:14 ni o tọ