Jẹnẹsisi 29:18 BM

18 Jakọbu nífẹ̀ẹ́ Rakẹli, nítorí náà, ó sọ fún Labani pé, “N óo sìn ọ́ ní ọdún meje nítorí Rakẹli, ọmọ rẹ kékeré.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 29

Wo Jẹnẹsisi 29:18 ni o tọ