Jẹnẹsisi 29:25 BM

25 Nígbà tí ó di òwúrọ̀, Jakọbu rí i pé Lea ni wọ́n mú wá fún òun. Ó bi Labani, ó ní, “Irú kí ni o ṣe sí mi yìí? Ṣebí nítorí Rakẹli ni mo fi sìn ọ́? Èéṣe tí o tàn mí jẹ?”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 29

Wo Jẹnẹsisi 29:25 ni o tọ