Jẹnẹsisi 3:10 BM

10 Ó dá Ọlọrun lóhùn, ó ní, “Nígbà tí mo gbúròó rẹ ninu ọgbà, ẹ̀rù bà mí, mo bá farapamọ́ nítorí pé ìhòòhò ni mo wà.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 3

Wo Jẹnẹsisi 3:10 ni o tọ