Jẹnẹsisi 30:13 BM

13 Lea bá ní, “Mo láyọ̀, nítorí pé àwọn obinrin yóo máa pè mí ní Ẹni-Ayọ̀,” nítorí náà ó sọ ọmọ náà ní Aṣeri.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 30

Wo Jẹnẹsisi 30:13 ni o tọ