Jẹnẹsisi 30:18 BM

18 Lea ní “Ọlọrun san ẹ̀san fún mi, nítorí pé mo fún ọkọ mi ní iranṣẹbinrin mi.” Ó bá sọ ọmọ náà ní Isakari.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 30

Wo Jẹnẹsisi 30:18 ni o tọ