Jẹnẹsisi 30:20 BM

20 Ó ní, “Ọlọrun ti fi ẹ̀bùn rere fún mi, nígbà yìí ni ọkọ mi yóo tó bu ọlá fún mi, nítorí pé mo bí ọkunrin mẹfa fún un,” nítorí náà ó sọ ọmọ náà ní Sebuluni.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 30

Wo Jẹnẹsisi 30:20 ni o tọ