Jẹnẹsisi 30:24 BM

24 Ó wí pé, “Ọlọrun ti mú ẹ̀gàn mi kúrò,” ó sọ ọmọ náà ní Josẹfu; ó ní, “Kí OLUWA má ṣàì fún mi ní ọmọkunrin mìíràn.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 30

Wo Jẹnẹsisi 30:24 ni o tọ