Jẹnẹsisi 30:27 BM

27 Ṣugbọn Labani dá a lóhùn pé, “Gbà mí láàyè kí n sọ ọ̀rọ̀ yìí, mo ti ṣe àyẹ̀wò, mo sì ti rí i pé nítorí tìrẹ ni OLUWA ṣe bukun mi,

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 30

Wo Jẹnẹsisi 30:27 ni o tọ