3 Rakẹli bá dáhùn, ó ní, “Biliha, iranṣẹbinrin mi nìyí, bá a lòpọ̀, kí ó bímọ sí mi lọ́wọ́, kí èmi náà sì lè ti ipa rẹ̀ di ọlọ́mọ.”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 30
Wo Jẹnẹsisi 30:3 ni o tọ