Jẹnẹsisi 30:41 BM

41 Nígbà tí àwọn ẹran tí ara wọ́n le dáradára láàrin agbo bá ń gùn, Jakọbu a fi àwọn ọ̀pá náà siwaju wọn, kí wọ́n lè máa gùn láàrin wọn.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 30

Wo Jẹnẹsisi 30:41 ni o tọ