1 Jakọbu gbọ́ pé àwọn ọmọ Labani ń sọ pé òun ti gba gbogbo ohun tíí ṣe ti baba wọn, ninu ohun ìní baba wọn ni òun sì ti kó gbogbo ọrọ̀ òun jọ.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 31
Wo Jẹnẹsisi 31:1 ni o tọ