Jẹnẹsisi 31:10 BM

10 “Ní àkókò tí àwọn ẹran náà ń gùn, mo rí i lójú àlá pé àwọn òbúkọ tí wọn ń gun àwọn ẹran jẹ́ àwọn tí àwọ̀ wọn dàbí ti adíkálà ati àwọn onífunfun tóótòòtóó ati àwọn abilà.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 31

Wo Jẹnẹsisi 31:10 ni o tọ