Jẹnẹsisi 31:13 BM

13 Èmi ni Ọlọrun Bẹtẹli, níbi tí o ti ta òróró sórí òkúta tí o sì jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún mi. Dìde nisinsinyii, kí o jáde kúrò ní ilẹ̀ yìí, kí o sì pada sí ilẹ̀ tí wọ́n gbé bí ọ.’ ”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 31

Wo Jẹnẹsisi 31:13 ni o tọ