24 Ṣugbọn Ọlọrun sọ fún Labani ará Aramea lóru lójú àlá, ó ní, “Ṣọ́ra, má bá Jakọbu sọ ohunkohun, kì báà jẹ́ rere tabi buburu.”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 31
Wo Jẹnẹsisi 31:24 ni o tọ