Jẹnẹsisi 31:34 BM

34 Rakẹli ni ó kó àwọn ère oriṣa náà, ó dì wọ́n sinu àpò gàárì ràkúnmí, ó sì jókòó lé e mọ́lẹ̀. Labani tú gbogbo inú àgọ́ rẹ̀, ṣugbọn kò rí wọn.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 31

Wo Jẹnẹsisi 31:34 ni o tọ