Jẹnẹsisi 31:7 BM

7 sibẹ, baba yín rẹ́ mi jẹ, ó sì yí owó ọ̀yà mi pada nígbà mẹ́wàá, ṣugbọn Ọlọrun kò gbà fún un láti pa mí lára.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 31

Wo Jẹnẹsisi 31:7 ni o tọ