Jẹnẹsisi 32:13 BM

13 Ó sùn níbẹ̀ ní alẹ́ ọjọ́ náà, ó sì mú ninu ohun ìní rẹ̀ láti fi ṣe ẹ̀bùn fún Esau arakunrin rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 32

Wo Jẹnẹsisi 32:13 ni o tọ