Jẹnẹsisi 32:17 BM

17 Ó sọ fún èyí tí ó ṣáájú patapata pé, “Nígbà tí Esau arakunrin mi bá pàdé rẹ, tí ó sì bi ọ́ pé, ‘Ti ta ni ìwọ í ṣe? Níbo ni ò ń lọ? Ta ló sì ni àwọn ẹran tí wọ́n wà níwájú rẹ?’

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 32

Wo Jẹnẹsisi 32:17 ni o tọ