22 Ní òru ọjọ́ náà gan an, ó dìde ó kó àwọn aya rẹ̀ mejeeji, àwọn iranṣẹbinrin mejeeji ati àwọn ọmọ rẹ̀ mọkọọkanla, ó kọjá sí ìhà keji odò Jaboku.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 32
Wo Jẹnẹsisi 32:22 ni o tọ