Jẹnẹsisi 33:1 BM

1 Bí Jakọbu ti gbé ojú sókè, ó rí Esau tí ń bọ̀ pẹlu irinwo (400) ọkunrin. Ó bá pín àwọn ọmọ rẹ̀ fún Lea ati Rakẹli, ati àwọn iranṣẹbinrin mejeeji.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 33

Wo Jẹnẹsisi 33:1 ni o tọ