Jẹnẹsisi 33:17 BM

17 Ṣugbọn Jakọbu lọ sí Sukotu o kọ́ ilé kan fún ara rẹ̀ ó sì ṣe àtíbàbà fún àwọn ẹran rẹ̀. Nítorí náà ni wọ́n Ṣe ń pe ibẹ̀ ní Sukotu.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 33

Wo Jẹnẹsisi 33:17 ni o tọ