Jẹnẹsisi 33:19 BM

19 Ó ra ilẹ̀ ibi tí ó pàgọ́ rẹ̀ sí ní ọgọrun-un (100) gẹsita lọ́wọ́ àwọn ọmọ Hamori, baba Ṣekemu.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 33

Wo Jẹnẹsisi 33:19 ni o tọ