7 Lea ati àwọn ọmọ rẹ̀ náà súnmọ́ wọn, àwọn náà wólẹ̀ fún un, lẹ́yìn náà ni Josẹfu ati Rakẹli súnmọ́ ọn, àwọn náà wólẹ̀ fún un bákan náà.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 33
Wo Jẹnẹsisi 33:7 ni o tọ