1 Ní ọjọ́ kan, Dina, ọmọbinrin tí Lea bí fún Jakọbu jáde lọ kí àwọn obinrin kan ní ìlú Ṣekemu.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 34
Wo Jẹnẹsisi 34:1 ni o tọ