23 Ṣebí gbogbo ẹran ọ̀sìn wọn, ati gbogbo ohun ìní wọn ni yóo di tiwa? Ẹ ṣá jẹ́ kí á gbà fún wọn, wọn yóo sì máa bá wa gbé.”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 34
Wo Jẹnẹsisi 34:23 ni o tọ