Jẹnẹsisi 35:18 BM

18 Nígbà tí ẹ̀mí rẹ̀ ń bọ́ lọ, kí ó tó kú, ó sọ ọmọ náà ní Benoni, ṣugbọn baba rẹ̀ sọ ọ́ ní Bẹnjamini.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 35

Wo Jẹnẹsisi 35:18 ni o tọ