Jẹnẹsisi 35:23 BM

23 Àwọn ọmọ Jakọbu jẹ́ mejila. Àwọn tí Lea bí ni: Reubẹni, àkọ́bí Jakọbu. Lẹ́hìn rẹ̀ ni ó bí Simeoni, Lefi, Juda, Isakari ati Sebuluni.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 35

Wo Jẹnẹsisi 35:23 ni o tọ