27 Jakọbu pada sọ́dọ̀ Isaaki, baba rẹ̀, ní Mamure, ìlú yìí kan náà ni wọ́n ń pè ní Kiriati Ariba tabi Heburoni, níbi tí Abrahamu ati Isaaki gbé.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 35
Wo Jẹnẹsisi 35:27 ni o tọ