Jẹnẹsisi 36:12 BM

12 (Elifasi, ọmọ Esau ní obinrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Timna, òun ni ó bí Amaleki fún un.) Àwọn ni àwọn ọmọ Ada, aya Esau.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 36

Wo Jẹnẹsisi 36:12 ni o tọ