Jẹnẹsisi 36:18 BM

18 Lára àwọn ọmọ Oholibama, aya Esau: àwọn tí wọ́n jẹ́ ìjòyè ni: Jeuṣi, Jalamu, ati Kora. Àwọn ni ìjòyè tí wọ́n ṣẹ̀ láti ọ̀dọ̀ Oholibama, ọmọ Ana, aya Esau.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 36

Wo Jẹnẹsisi 36:18 ni o tọ